*AKOSORI YORUBA FUN GBOGBO OMO KAARO OOJIIRE* (ENGLISH TRANSLATION)

*ISÉ NI ÒÒGÙN ÌSÉ*
Work is the antidote for poverty.
*MÚRA SÍ ISÉ RE, ÒRÉÈ MI*
Work hard, my friend.
*ISÉ NI A FI Í DI ENI GIGA*
work is used to elevate one in respect and importance
(Aspiring to higher height is fully dependent on hard work).
*BÍ A KÒ BÁ RÉNI FÈYÌN TÌ, BÍ ÒLE LÀ Á RÍ*
if we do not have anyone to lean on, we appear indolent.
*BÍ A KO RÉNI GBÉKÈLÉ*
if we do not have anyone to trust (we can depend on).
*À A TERA MÓ ISÉ ENI*
we simply work harder.
*ÌYÁ RE LÈ LÓWÓ LÓWÓ*
your mother may be wealthy.
*BÀBÁ SÌ LÈ LÉSIN LÉÈKÀN*
your father may have a ranch full of horses.
*BÍ O BÁ GBÓJÚ LÉ WON*
if you depend on their riches alone.
*O TÉ TÁN NI MO SO FÚN O*
you may end up in disgrace, I tell you.
*OHUN TÍ A KÒ BA JÌYÀ FÚN*
whatever gain one does not work hard to earn.
*KÌ Í LÈ TÓJÓ*
usually does not last.
*OHUN TÍ A BÁ FARA SISÉ FÚN*
whatever gain one works hard to earn.
*NÍ Í PÉ LÓWÓ ENI*
is the one that lasts in one’s hands (while in ones
possession).
*APÁ LARÁ*
the arm is a relative
*ÌGÙNPÁ NÌYEKAN*
the elbow is a sibling.
*BÍ AYÉ N FÉ O LÓNÌÍ*
you may be loved by all today.
*BÍ O BÁ LÓWÓ LÓWÓ*
it is when you have money.
*NI WON Á MÁA FÉ O LÓLA*
that they will love you tomorrow.
*TÀBÍ TÍ O BÁ WÀ NÍ IPÒ ÀTÀTÀ*
or when you are in a high position.
*AYÉ Á YÉ O SÍ TÈRÍN-TÈRÍN*
all will honor you with cheers and smiles.
*JÉ KÍ O DI ENI N RÁÁGÓ*
wait till you become poor or are struggling to get by.
*KÍ O RÍ BÁYÉ TI Í SÍMÚ SÍ O*
and you will see how all grimace at you as they pass you by.
*ÈKÓ SÌ TÚN N SONI Í DÒGÁ*
education also elevates one in position.
*MÚRA KÍ O KÓ O DÁRADÁRA*
work hard to acquire good education.
*BÍ O SÌ RÍ ÒPÒ ÈNÌYÀN*
and if you see a lot of people.
*TÍ WÓN N FI ÈKÓ SE ÈRÍN RÍN*
making education a laughing stock.
*DÁKUN MÁ SE FARA WÉ WON*
please do not emulate or keep their company.
*ÌYÀ N BÒ FÓMO TÍ KÒ GBÓN*
suffering is lying in wait for an unserious kid.
*EKÚN N BE FÓMO TÓ N SÁ KIRI*
sorrow is in the reserve for a truant kid.
*MÁ FÒWÚRÒ SERÉ, ÒRÉÈ MI*
do not play with your early years, my friend.
*MÚRA SÍSÉ, OJÓ N LO*
work harder; time and tide wait for no one.
Let’s pass it on to our children.
Original work by *J F Odunjo*

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s